ALFA TAPA
Spiritual problems Solution and so on
OBINRIN TIN YA ALE
OBINRIN TI N DOKO TABI OBINRIN TI N YAN ALE
igbe adie ori aba
Asa ibile ti won ma fin
Ori
Ao po gbogbo re papo sinu ike kekere olomori
Okunrin yio ma fi pa nkan omokunrin re, yio ma fi ba iyawo re sun
PELU OGO OLOHUN OBINRIN NA KO NI YAN ALE MO
ALFATAPA
08124002628
08107555203
27/03/2026
EBE AWON AGBA
Ewe imi esu
Odidi atare
Ao jopo, ao lo kunna
Ao po mo ori tabi epo pupa
Ao ma fi para
ALAFA TAPA
08124002628
08107555203
EYONU TI OMO ARAYE FI YONU SIWA
ISOYE
OHUN SISE FUN OMODE ATI AGBALAGBA TI WON MA N GBAGBE OHUN TI WON KO WON NI ILE IWE TABI ILE KEWU, TABI GBOGBO NKAN TI A BA KO @
EFORI,ORIFIFO/ HEADACHE
TI EBA GBIYANJU ASIRI YI ORI FIFO DAGBERE NINU AYE ENI BE ,viral,alfatapa
22/03/2026
OGUN EYONU
Odidi eye elulu
Ewe lapalapa funfun
Ao jo papo
Ao lo yio kunna
Ale fi omi lasan lo tabi ki a fi foko tutu mu
ALFA TAPA
08124002628
08107555203
22/03/2026
ISOYE OMODE PELU AGBALAGBA
Odidi eye elulu kan
Ewe oniyemiye
Ao jo papo
Omode pelu agbalagba yio ma fi foko tutu mu siwaju ki won to jeun aro
ALFA TAPA
08124002628
08107555203
22/03/2026
OGUN EFORI TULU TABI ORI FIFO
Ori eye elulu kan
Odidi atare kan
Ao jo papo
Ao fi singbere kan si awuje oni tohun
Ori fifo dagbere ninu aye eni be
ALFA TAPA
08124002628
08107555203
20/03/2026
Eid Mubarak
Click here to claim your Sponsored Listing.
Category
Contact the business
Telephone
Website
Address
Ibadan
