Tito TV
A lover of God creating content
l share relatable contents Daily prayers in Yorùbá and English that can help your day by day life journey.
remember the best is yet to come 🙏🏻
Subscribe to get exclusive benefits:
https://www.facebook.com/61560650134025/subscribenow
Nínú gbogbo irinajo rẹ nínú ọ̀sẹ̀ yi Ọlọ́run a lànà fún yín tomotomo Àmín
Please like and share to your family and friends God bless you all Amen 🙏🏻
Ire,Ayọ to lérò nínú ọ̀sẹ̀ yi a Ọ lọwọ Amin 🙏🏻
05/10/2026
Nínú ọ̀sẹ̀ yi èmi àti ìwọ a rí batise a rí ọ̀nà gbe gbà láṣẹ Èdùmàrè Àmín
04/10/2026
Gbogbo ìwọ abiyamo tó ba bá àwòrán yí padà wọn ní torí Ọmọ rẹ kàn posi ibanuje láṣẹ Èdùmàrè Àmín
04/10/2026
Gbogbo ìwọ abiyamo tó tẹ Àmín sì Adura yi iná Ọmọ kò ní jo yín láṣẹ Èdùmàrè Àmín
04/10/2026
This week is your week in Jesus mighty name 🙏🏻
Sunday àkókò nínú oṣù (OCTOBER)
Ògo ní fún Ọlọ́run lókè ọrùn
🙌🙌🙌🙌🙌🙌🙌
èmi wá a ṣe púpò rẹ láyé Amin loruko Jesu Kristi 🙏🏻
Òni ni Ọjọ ìsinmi olúwa
A kú ìsinmi Òni o èmi gbogbo wá a ṣe púpò rẹ láyé nínú àlàáfíà àti ifọkanbalẹ láṣẹ Èdùmàrè Àmín 🙏🏻
Oru ayò là má su
Layọ là má jí lowurọ ọlá
A ní jì sínú ibanuje àti idamu láṣẹ Èdùmàrè Àmín
Click here to claim your Sponsored Listing.
Address
Lagos Harbour
11011
Alerts
Be the first to know and let us send you an email when Tito TV posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.
