ASEDA

ASEDA

Share

fadipe Omo aseda .I am traditionalist .esu Nation..

13/06/2026
12/06/2026

AWON ONA TI AJE (WEALTH) FI MA NKURO LARA ENIYAN
Aje yi je spirit kan toma nsise owo wafun eda eniyan, ti ogo eniyan sima tete buyo ise keke re owo nla, koda eniyan lema ni ise gidi kan lowo ti owo asima wole ni onakona, eniyan ti spirit aje ba wa ni ara re tikosi je ewo(forbidden) aje tabi awon ti ika eda kofi oju si lara debi tiwon madena lati ri aje re lo, iru eniyan be oma ri owo ni ona tiko ro rara... Iru won ni won ma ntete ni owo lowo... Ni owo toje owo nla....
Eniyan toba ri aje lo, koni damu laiye kio to ni owo gidi lowo....
Àjé je nkan pàtàkì tii kii kúrò lára ẹniyan niwọn bá igba tii ẹda bati tètè se iwadi irawo re ati akosejaiye re kiole ma nkan toye komase...

BAWONI AJEH(WEALTH) SE MA NKURO LARA ENIYAN?

nje iwo mape aje ama kuro lara eyan tiosi fi eniyan sile patapata....
-Ti eyan koba se awari ara re debi tikoma awon nkan totako irawo ati kádàrá re, tori gbogbo eda loni awon asiri topamo sinu kakara won ... Osese ki aje fi oni tohun sile patapata....

-Awon agbalagba ama se akoba fun irawo elomi, tiwon madena atiri aje ara re lo, iru awon eniyan yi ni ogun idile abi ogun aiye ndamu....

-Ofa aiye wa lara elomiran tikoni je kio ri aje re lo... Gbogbo igbinyanju re koni yo tori ofa aiye towa lara re...

-Elomiran tije ewo irawo re, eleyi madena lati ri aje re lo, gbogbo igba toba tin se nkan totako irawo re ni ona atilosi waju lenu ise tabi ninu aje madiku.....

-Nje eyin mape kise gbogbo omo léle yokuro ninu egbe.... Ojo tiwon tiyo omo miran kuro ninu egbe ni aje tikuro larare tori aje to nlo ninu egbe lowa... Idi niyi ti opolopo awon omo elegbe fi ma n ni aje lara tori egbe loni aje tiwon nlo....

-ewo aje (wealth)... Aje gan gan fun rara re ni ewo tie.... Sugbon koye opolopo eniyan, gbogbo igba toba tin se nkan ti aje kofi arama ni aje atima fi onitohun sile, aje ni ewo ode ni itoju tie....

-ninu nkan totun ma nfa ki aje kuro lara eniyan ni ibalopo (S×X) kise gbogbo eniyan logbodo ma gun orire gege bi omo alaje tioje... Kisise gbogbo eniyan ni olema bani ajosepo.. Aje kofi arama gbogbo awon nkan won yi... Oropo ninu iwe kobo....
ETC....
Eje Kin Nda Owo(✍️) Duro Bayen Na....

NINU AWON TOPIC TO NBO LONA 👇

ERISIRISI AJEH (WEALTH) WEALTH LOMA NWA LARA ENIYAN
-IGBA AJEH!
-OPA AJEH!
-A*O AJEH!
-OMO AJEH!
-IGI AJEH!
-IRANSE AJEH!.....COMING SOON

ETC....
Eje Kin Nda Owo(✍️) Duro Bayen Na....


MOSE IBA AGBA 🙌

FUN IBERE TABI IWADI NIPA IRAWO ATI AKOSEJAIYE RE... MESSAGE ME ON WHATSAPP WITH THE NUMBER
08033784377
FADIPE ASEDA CARE

Want your business to be the top-listed Beauty Salon in Lagos?
Click here to claim your Sponsored Listing.

Telephone

Website

Address


Lagos