Sheik onike
Contact information, map and directions, contact form, opening hours, services, ratings, photos, videos and announcements from Sheik onike, Health/Beauty, Saki.
18/08/2026
LATEEF ROJIHI لطيف رجوع %
LATEEF ROJIHI لطيف رجوع
Awon agbalagba npe asiri Kan ni lateef rojihi لطيف رجوع asiri yin lagbara pupo awon agbalagba ma fi da nkan pada...boya won ji eniyan gbe (kidnap) afe ki won dapa tabi won ji nkan gbe (stealing something) or won sack enikan Nibi ise afe kiwon dapada tabi iyawo Kan fiwasile afe kopada tabi omo Kan sa kuro nile afe kopada sile....tabi enikan gbe owo money wa salo...afe Koda owo naa pada tabi enikan je wa ni owo afe kodapa ti aba Fe da nkan pada lama lo asiri yin mujarab ni..asiri yin kise asiri Ori afefe...
A o se aluwala a o wo a*o funfun a o fi turari oloru Sara a o wa Yan nafilah meji a o salamo a ose mukodimat a o wa daniyan a o gbe alquran a o si suratul kahaf سورۃ الكهف a o ma ka ti aba ti de ibi wali yatalatofu وليتلطف a o duro sibe a o wa se yah lateef 16857..يالطيف 16857 ti aba tiparire a o wa daniyan Lori nkan ti afe kiwon dapa a o wa pari suratul kahaf dele a otun da aniyan wa pada....ti ABA tise tan opari....ejeki asa iseyin fun ojo meta pere leyin ojo keta a o se Sara re....agbon iyekiye..epa jije iyo agbado a o fi se Sara re opari inshallah ise todaju ni Walahi talahi asiri Inu Ile ni...enikeni tobasa iseyin tikobari gbigba adura re haaa ki eni naa komu ra dada....ide pofun ni....olohun ajeki o je funwa Inshallah... Barakalahun fihi
07089955289 W & C
07035001257 Alfa onike my WhatsApp number..
Alfa Muhammed onike ❤️
18/08/2026
NAFILAH TI A FI N SEGUN ATI LATIFI BORI AWON OTAWA TABI AWON TI WON DA AYEWA LAAMU...
Asiri yin lagbara pupo kosi ogun kogun ti nafilah yin kole se fun eniyan....ojo ti aba ti bere nafilah yin naani a o ti Mari awon apeere isegun... gbogbo Iwo ti aye re konitumo tabi awon agbalagba n dalaamu abi gbogbo nkan lotise ayere koyato abi Iwo to tun Fe ba aye awon otare je....Dan nafilah naa wo....edakun emajeki afi nafilah yin sere..emajeki wa lazy elomiran le sope nafilah poju hmmm enitobafeje eniyan pelu igbinyaju ni...
A o Yan nafilah merin
Nafilah akoko leyin suratul fatiah Kan suratul lahab(tabatiyadah 400) Yah dafiu li afati 100
Nafilah elekeji leyin suratul fatiah Kan suratul lahab 300 ( tabatiyadah 300) Yah dafiu li afati 100
Nafilah eleketa leyin fatiah Kan suratul lahab 200 ( tabatiyadah 200) Yah dafiu li afati 100
Nafilah elekerin leyin suratul fatiah Kan suratul lahab 100 (tabatiyadah 100). Yah dafiu li afati 100..
A o salamo leyin salamo a o ka kewu yi
Allahumo fariji hami wakasifi gami wahalaka aduwiy 100
A o daniyan edakun ejeki a gbinyaju nafilah yin fun ojo meje edakun emajeki o ja rara hmmm kotope ojo meje laotimari isegun Walahi talahi iseni gbogbo enu ni mofi so....asiri to segun ota ni..
Note...edakun mofe ki a gbinyaju nafilah yin ni...Walahi kopo rara kise nafilah toma gba eniyan ni asiko pupo...ejowo edakun 🙏..olohun ri aniyan mi opolopo lo complain Nipa olota de...mofi asiri yin sewa ni aanu ni...olohun ajeki o je funwa 🙏
Ose apota buruku pupo to n ba aye ota je hmmm loadin...
07035001257 whatshap number
Alfa Muhammed onike ❤️🙏
17/08/2026
ASIRI LATEEF FUN OWO NLA
Asiri lateef po gidi lorisirisi ona bi a nse lo siru lateef lodo eyin agbalagba kosi Ara tiwon kifi lateef da fun awon tiwon ba mo lateef dada...ninu ona bi ase lo siru lateef ni eleyi asiri yin daju fun eni ti o bawa owo..fun eni tobaje gbese tabi afesan owoile tabi afe San owo school tabi ona nje imu din funwa ejeki a gbinyaju asiri Walahi talahi o koja iroyin ninu group alubarika yin akifi ise tikoba pe kale ama fi isekale Tori tolohun ni....
Ejeki a wa owo #1000 tabi #500 a o la khatimi yin sinu owo tio bawuwa ti abafelo TI ABA ti la khatimi yin si oju owo yin tan ejeki a sun owo yin ni Ina erun owo yin ejeki a dasinu Ike funfun kekere Kan ki awa da oyin ojuda si....a o ma la kinni yin ti aba ti Fe bere adura...ojo Sunday lama nbere adura yin a o se fun 7 or 11 or 21 days leyinna ejeki ama fi agbado ati okababa se Sara lojojumo....iseyin daju pupo olohun ajeki o jefunwa.... barakalahun fihi
07089955289 W &C
07035001257 W
Alfa Muhammed onike ❤️
16/08/2026
ASIRI DALAELUL KHAIRAT FUN OWO NLA MUJARAB.
Asiri dalaelu khairah po lorisirisi lodo eyin agbalagba but mafi orisisi meji kale fun Iwo ti olohun bakadara ki o le danwo ti o kise ole Alfa Walahi talahi tobagbinyanju ise wa dupe ninu ayere.....ha iseyin daju pupo..
اللهم صل علی محمد وسلم ٥۰۰ 500
A o han ni asalatu yi ni 500 lona meji pelu khatimi Kan sinu opon ola a o wa fo si ona ototo sinu Ike otooto...a o fi okan se eyele funfun a o gesi 16 a ose pelu iyere ati Omi hantu Kan leponiyo je ni ojo Monday lamase a maje ti aba tijetan...hantu idakeji a o fo eyin adie abalaye Kan si pelu peak milk ati oyin si a o ro papo a o mule aseje yan a wa mule aseje yin....opari a o wa bere adura re..
A o wa ni mimo a o wo a*o funfun a o fi turari Toni oru pa gbogbo arawa ale tan turari onigi naa a owa bere adura yin leyin mukodumat a o bere khutubah ibtdahi leyin a o ka isbi dalaelu ojo Monday leyinna a o ka suratul re a o ka khutubah khatamah ise ojo Yan tipari niyan..bee la o se Mase ise ojo kookan ni ojojumo bosewa ninu tira Yan.... tobajewipe ojo meje lafefise oma pari lojo Sunday tobajewipe ojo mejo omapari ni Monday. A o wase sarare boya kapa adie Akuko tabi pepeye tabi eran Walahi odaju pupo ebami danwo eleyi kuro ni Oro enu.....
Miki post ise ti kobape gbogbo ise Timo ba post Walahi talahi awon eniyan ma n dupe pupo Koda awon elomiran ma send owo tabi card simi ebami confirm iseyin wo....
MAJEMU ISEYIN DAKUN BAMI SE ASALATU FUN ANABI LABE COMMENT....
07035001257 W
07089955289 W & C
16/08/2026
SURATUL WAKIAH FUN ASEJE OWO NLA TO CONFIRM %....
A o han suratul wakiah meje sinu opon ola ti aba ti Han ayah kookan suratul wakiah a o ma han aya yin
نصر من اﷲ وفتح قريب وبشير للمومنين
A o ma Han ayah yi kokan si ayah Surat wakiah t**i yoo fipe wakiah meje ti aba Han tan a o wa fo pelu Omi to mo dada a o wa ahun maalu oojo a o gesi 16 a o dasinu isasun tuntun tolegba a o wa ewe aje....ewe aanu....iyere a o lo papo a o da*ori aseje yin a o wa fi hantu wakiah Yan se lepo niyo tobatijina a o so sori osuka funfun a o wa ni mimo a o je pelu adura Walahi talahi a o sebi ase ogun owo ni iseyin daju pupo...yatosi iwakuwa kiri iseyin daju pupo...ejeki a gbinyaju rewo ti abafese ejeki ariwipe awon tiwon ma bawa hantu kiwon hantu yin kope dada ti hantu yan ko ba pe konisise dada bi a sefe....olohun agbafunwa..........
07089955289 W & C
07035001257 W
Alfa Muhammed onike ❤️
16/08/2026
KHATIMI ODIDI ALQURAN
Khatimi yin duro fun odidi alquran ki isorokisoro tikoyanju gbogbo lese ni kosi ona ti alegba lo... gbogbo ise lonse osise tude..osise Asina owo..etc..ejeki han sinu opon ola ki afi aniyan tobawuwasi sugbon aniyan bibo asiri lemi fisi tobawuwa alefi aniyan iso tabi ISEGUN ota si ejeki a fi Omi Tomo dada fo ki awafi oyin si ejeki a mu ti abatife sun ni ale pelu aniyan nkan ti a need....ti abatimu tan ejeki a losun ejeki amase be lojojumo fun 7days.. olohun ajeki o je funwa odaju pupo
07089955289 W & C
07035001257 W
Alfa Muhammed onike ❤️
05/08/2026
BIBO ASIRI OWO TODAJU
Asiri yin daju pupo mo ti post asiri yin sori tik Tok page(Sheik Onike) me ri ti opolopo awon eniyan comfirm re ejeki awa naa gbinyaju re fun gbogbo awa ti a o ti Dan asiri yin wo....a o wa 1000 new notes a o la khatimi yin si a o wa Jo owo naa eeru (Ash) owo naa ama da sinu lofinda bintu sundan tabi six flowers a o ma fi pa gbogbo arawa leyin ti atise aluwala a o wa ma se adura re lojojumo...
Leyin nafilah meji a o se mukodimat a o wa daniyan a o wa bere adura re ni onka 313 a o Mase lojojumo ni aro Walahi talahi mujarab ni.....
ماعندكم ينفد وما عند ﷲ باق 313
barakalahun fihi
Alfa Muhammed onike ❤️
04/08/2026
SIRU AYYATUL KURISY MUJARAB
Ti idiwo bapo ju Lara tabi aisan Kan dawa laamu tabi ide buruku emi buruku Kan n dawalaamu etc...ejeki a gbinyaju asiri yin...Koda ki a mala alakala ounje oju oru ibalopo oju etc...
A o Han ayatul kursy meje pelu khatimi re Kan a o wa fo pelu Omi die....tobadi ale a o wa mu ninu hantu yin a o fi iyoku pa gbogbo arawa a o wa losun...a o ma hantu Yan bee lojojumo fun ojo meje tabi ki a Han kale ki amalo lojojumo fun ojo meje Walahi talahi mujarab ni....kurys meje pelu khatimi Kan fun ojo Kan ni ooo...... barakalahun fihi
07035001257
07089955289
tiktok Account Sheik Onike
Alfa Muhammed onike
04/08/2026
BIBO ASIRI OWO KIAKIA
IT BEEN A WHILE HERE....Emabinu mo busy die ni.....becoz ki eniyan to le type eniyan gbodo wa aye dada.....mofe ki a gbinyaju asiri yin olagbara pupo gidi......asiri wa ma no lonakona ni.....asiri yin ni oga ma n wi ti asiri re ki fi tu rara.....a o Han kewu yin
اللهم استرني بسترك الجميل 313
pelu khatimi re ni 66 sinu opon ola tabi ki a print re eyitoba easy funwa a o wa fo pelu Omi toba po dada a o wa Mamu die nibe a o ma fi parawa lasiko adura...kosi time talese adura yin a o wa Mase adura re ni 313 lojojumo fun ojo meje tabi 21 or 41days Walahi talahi asiri wa koni tu layelaye....
bakanna atunle Han kewu yi
اللهم استرني بسترك الجميل 313
a o wa fi Omi die fo a o wa orogbo gbigbe meta tabi meje a o wa kosinu Ike funfun a o wa da Omi hantu Yan lelori a o wa depa a o wa fi kale ki orogbo yan fi fa gbogbo Omi hantu Yan mu leyinna a o wa lo gbogbo orogbo yan kunna dada ejeki a ma da sinu lofinda tabi cream wa K**a fi pa gbogbo arawa Jade Walahi talahi asiri wa koni tu mujarab ni....ebami danwo
u can follow me on my tiktok
Sheik Onike
07089955289
07035001257
Alfa Muhammed onike
IFERAN MUNUYO...MABINUSIMIMO TOYANJU
Click here to claim your Sponsored Listing.
Category
Website
Address
Saki
